Publications
Àsọyé níbi àpérò àgbáyé ní Baghdad lórí bí àwọn orílẹ̀-èdè tó ń wá òmìnira ṣe lè fọwọ́sowọ́pọ̀.
A gbó ọ̀rọ̀ pàtàkì níbi àpérò ní Baghdad nípa bí ìṣọ̀kan ṣe jẹ́ ọ̀nà láti borí gbogbo àwọn aláfipájẹgàba lórí àwọn orílẹ̀-èdè tó ń jà fún òmìnira.